Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa National Sins: Sodom and Gomorrah

2 ẹsẹ · 34 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sodom and Gomorrah

  1. Olúwa sì wí pé, igbe Sodomu àti Gomorra pọ̀ púpọ̀ àti pé ẹ̀ṣẹ̀ wọn burú jọjọ.

  2. Tí ó sọ àwọn ìlú Sodomu àti Gomorra di eérú, nígbà tí ó fi ìparun pátápátá dá wọn lẹ́bi, tí ó fi wọ́n ṣe àpẹẹrẹ fún àwọn tí yóò jẹ́ aláìwà-bí-Ọlọ́run.