Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa National Sins: Nations of Canaan

1 ẹsẹ · 34 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Nations of Canaan

  1. Lẹ́yìn tí Olúwa Ọlọ́run yín bá ti lé wọn jáde níwájú u yín, ẹ má ṣe wí fún ara yín pé, “Torí òdodo mi ní Olúwa ṣe mú mi wá síbí láti gba ilẹ̀ náà.” Rárá, ṣùgbọ́n nítorí ìwà búburú àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí ni Olúwa yóò ṣe lé wọn jáde níwájú u yín.