Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Thunder and rain in harvest
Àwọn ẹsẹ nípa Thunder and rain in harvest
Nígbà náà ni Samuẹli ké pe Olúwa, Olúwa sì rán àrá àti òjò ní ọjọ́ náà. Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ènìyàn sì bẹ̀rù Olúwa àti Samuẹli púpọ̀.