Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Death of Sapphira
Àwọn ẹsẹ nípa Death of Sapphira
Lójúkan náà ó sì ṣubú lulẹ̀ lẹ́sẹ̀ rẹ̀, ó sì kú; àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì wọlé wọ́n bá a ní òkú, wọ́n sì gbé e jáde, wọ́n sín in lẹ́bàá ọkọ rẹ̀.