Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Water from rock in Kadesh
Àwọn ẹsẹ nípa Water from rock in Kadesh
Nígbà náà ni Mose gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè ó sì fi ọ̀pá ọwọ́ rẹ̀ lu àpáta lẹ́ẹ̀méjì. Omi sì tú jáde, gbogbo ìjọ ènìyàn àti àwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì mu.