Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Healing by brazen serpent
Àwọn ẹsẹ nípa Healing by brazen serpent
Olúwa sọ fún Mose pé, “Rọ ejò, a ó sì gbé e kọ́ sókè lórí igi, ẹni tí ejò bá ti gé jẹ lè wò ó yóò sì yè.”
Nígbà náà ni Mose sì rọ ejò onírin ó sì gbé e kọ́ sórí igi, bí ejò bá sì bu ẹnikẹ́ni jẹ bí ó bá ti wò ó yóò sì yè.