Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Rod restored
Àwọn ẹsẹ nípa Rod restored
Nígbà náà ni Olúwa wá sọ fún un pé, “Na ọwọ́ rẹ, kí o sì mú un ni ìrù.” Mose sì na ọwọ́ rẹ̀, ó sì mu ejò náà, ejò náà sì padà di ọ̀pá tí ó wà ni ọwọ́ rẹ̀.