Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Miracles Wrought Through Servants of God: Darkness brought
Àwọn ẹsẹ nípa Darkness brought
Nígbà náà ni Mose gbé ọwọ́ rẹ sókè sí ojú ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì bo gbogbo ilẹ̀ Ejibiti fún ọjọ́ mẹ́ta. Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Israẹli ní ìmọ́lẹ̀ ní ibi tí wọn ń gbé.