Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Dan: Bounds of its inheritance
Àwọn ẹsẹ nípa Bounds of its inheritance
Ìbò kéje jáde fún ẹ̀yà Dani, ní agbo ilé ní agbo ilé.
Ilẹ̀ ìní wọn nìwọ̀nyí: Sora, Eṣtaoli, Iri-Ṣemesi,
Ṣaalabini, Aijaloni, Itila,
Eloni, Timna, Ekroni,
Elteke, Gibetoni, Baalati,
Jehudu, Bene-Beraki, Gati-Rimoni,
Me Jakoni àti Rakkoni, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó kọjú sí Joppa.