Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Asher

29 ẹsẹ · 21 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Beseri, Hodi, Ṣamma, Ṣilisa, Itrani àti Bera.

  2. Àwọn ọmọ Jeteri: Jefunne, Pisifa àti Ara.

  3. Àwọn ọmọ Ulla: Arah, Hannieli àti Resia.

  4. Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Aṣeri—olórí ìdílé, àṣàyàn ọkùnrin, alágbára jagunjagun àti olórí nínú àwọn ìjòyè. Iye àwọn tí a kà yẹ fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti ṣe kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlá (26,000) ọkùnrin.