Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serpents: Many kinds of poisonous

2 ẹsẹ · 26 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Many kinds of poisonous

  1. Èmi yóò mú wọn gbẹ, ooru gbígbóná àti ìparun kíkorò ni a ó fi run wọ́n. Pẹ̀lú oró ohun tí ń rákò nínú erùpẹ̀.

  2. Oró wọn dàbí oró ejò, wọn dàbí adití ejò paramọ́lẹ̀ tí ó di ara rẹ̀ ni etí,