Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanctification: Through the word of God

3 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Through the word of God

  1. Sọ wọ́n di mímọ́ nínú òtítọ́, òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ.

  2. Èmi sì ya ara mi sí mímọ́ nítorí wọn, kí a lè sọ àwọn tìkára wọn pẹ̀lú di mímọ́ nínú òtítọ́.

  3. Kí òun lè sọ ọ́ di mímọ́ lẹ́yìn tí ó tí fi ọ̀rọ̀ wẹ̀ ẹ́ nínú agbada omí.