Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanctification: Holiness
Àwọn ẹsẹ nípa Holiness
Ṣùgbọ́n báyìí, ẹ ti bọ́ kúrò lọ́wọ́ agbára ẹ̀ṣẹ̀, ẹ sì ti di ẹrú Ọlọ́run àwọn ìbùkún rẹ̀ sí yin ni ìwà mímọ́ àti ìyè tí kò nípẹ̀kun.
Nítorí náà ẹ má ṣe jẹ́ alájọpín pẹ̀lú wọn.
Nítorí ẹ̀yin tí jẹ́ òkùnkùn lẹ́ẹ̀kan ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ẹ̀yin dí ìmọ́lẹ̀, nípa tí Olúwa: ẹ máa rín gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ ìmọ́lẹ̀
(nítorí èso Ẹ̀mí ni ìṣoore, àti òdodo àti òtítọ́).