Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanctification: Tabernacle sanctified by God's presence

3 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Tabernacle sanctified by God's presence

  1. níbẹ̀ sì tún ni èmi yóò pàdé àwọn ọmọ Israẹli, a ó sì fi ògo mi ya àgọ́ náà sí mímọ́.

  2. Nígbà náà ni àwọsánmọ̀ bo àgọ́ àjọ, ògo Olúwa bo àgọ́ náà.

  3. Mose kò sì lè wọ inú àgọ́ àjọ, nítorí àwọsánmọ̀ wà ní orí àgọ́, ògo Olúwa sì ti kún inú àgọ́ náà.