Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanctification: Is separation to the service of God

2 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Is separation to the service of God

  1. Ṣùgbọ́n kí ẹ mọ̀ pé, Olúwa ti ya ẹni olódodo sọ́tọ̀ fún ara rẹ̀; Olúwa yóò gbọ́ nígbà tí mo bá pè é.

  2. Nítorí náà, “Ẹ jáde kúrò láàrín wọn, kí ẹ sì yá ara yín si ọ̀tọ̀, ni Olúwa wí. Ki ẹ má ṣe fi ọwọ́ kan ohun àìmọ́; Èmi ó sì gbà yín.”