Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sanctification: In Christ

1 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In Christ

  1. Sí ìjọ ènìyàn Ọlọ́run ni Kọrinti, sí àwọn ti a sọ di mímọ́ nínú Kristi Jesu àti àwọn ti a pè láti jẹ́ mímọ́ pẹ̀lú gbogbo ènìyàn ni ibikíbi ti ń pe orúkọ Olúwa wa Jesu Kristi ẹni ti ń ṣe Olúwa tiwọn àti ti àwa náà: