Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Murder: The Herods
Àwọn ẹsẹ nípa The Herods
Nígbà tí Herodu rí í pé àwọn amòye náà ti tan òun jẹ, ó bínú gidigidi, ó sì pàṣẹ kí a pa gbogbo àwọn ọmọkùnrin tí ó wà ní Bẹtilẹhẹmu àti ní ẹkùn rẹ̀ láti àwọn ọmọ ọdún méjì sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi àkókò tí ó ti fi ẹ̀sọ̀ ẹ̀sọ̀ béèrè lọ́wọ́ àwọn amòye náà.
Nítorí náà, a bẹ́ orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú ilé túbú.
Ó sì fi idà pa Jakọbu arákùnrin Johanu.