Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Murder: Herodias and her daughter

4 ẹsẹ · 88 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Herodias and her daughter

  1. Pẹ̀lú ìmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ ìyá rẹ̀, ó béèrè pé, “Fún mi ni orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú àwopọ̀kọ́”.

  2. Inú ọba bàjẹ́ gidigidi, ṣùgbọ́n nítorí ìbúra rẹ̀ àti kí ojú má ba à tì í níwájú àwọn àlejò tó wà ba jẹ àsè, ó pàṣẹ pé kí wọ́n fún un gẹ́gẹ́ bí o ti fẹ́.

  3. Nítorí náà, a bẹ́ orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú ilé túbú.

  4. A sì gbé orí rẹ̀ jáde láti fi fún ọmọbìnrin náà nínú àwopọ̀kọ́, òun sì gbà á, ó gbé e tọ ìyá rẹ̀ lọ.