Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moabites: David takes refuge among, from Saul

2 ẹsẹ · 56 abala

Àwọn ẹsẹ nípa David takes refuge among, from Saul

  1. Dafidi sì ti ibẹ̀ náà lọ sí Mispa tí Moabu: ó sì wí fún ọba Moabu pé, “Jẹ́ kí baba àti ìyá mi, èmi bẹ̀ ọ́ wá bá ọ gbé, títí èmi yóò fi mọ ohun ti Ọlọ́run yóò ṣe fún mi.”

  2. Ó sì mú wọn wá síwájú ọba Moabu; wọ́n sì bá á gbé ní gbogbo ọjọ́ tí Dafidi fi wà nínú ihò náà.