Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moabites: Balak calls for Baalam to curse Israel

2 ẹsẹ · 56 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Balak calls for Baalam to curse Israel

  1. Nígbà tí Balaki ọmọ Sippori, ọba Moabu, múra láti bá Israẹli jà, ó ránṣẹ́ sí Balaamu ọmọ Beori láti fi yín bú.

  2. Ìwọ ènìyàn mi, rántí ohun tí Balaki ọba Moabu gbèrò àti ohun tí Balaamu ọmọ Beori dáhùn. Rántí ìrìnàjò rẹ̀ láti Ṣittimu dé Gilgali, kí ìwọ ba le mọ òdodo Olúwa.”