Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moabites: Separated from the Amorites by the river Arnon
Àwọn ẹsẹ nípa Separated from the Amorites by the river Arnon
Láti ibẹ̀ lọ, wọn ṣí, wọ́n sì dó sí ìhà kejì Arnoni, tí ó wà ní aginjù tí ó wà ní agbègbè ilẹ̀ àwọn ọmọ Amori. Arnoni jẹ́ ààlà fún ilẹ̀ Moabu, láàrín Moabu àti Amori.