Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moabites: To destroyed in three years
Àwọn ẹsẹ nípa To destroyed in three years
Èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa Moabu.
Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí Olúwa wí pé, “Láàrín ọdún mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ìdè ọgbà rẹ̀ ti máa kà á, ògo Moabu àti àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn rẹ̀ ni a ó kẹ́gàn, àwọn tí ó sálà nínú rẹ̀ yóò kéré níye, wọn yóò sì jẹ́ akúrẹtẹ̀.”