Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Moabites: King of, sacrificed his son to excite animosity against Israel

1 ẹsẹ · 56 abala

Àwọn ẹsẹ nípa King of, sacrificed his son to excite animosity against Israel

  1. Nígbà náà ó mú àkọ́bí ọmọkùnrin rẹ̀, tí kò bá jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọba, ó sì fi rú ẹbọ sísun ní orí ògiri ìlú. Wọ́n sì bínú lórí Israẹli púpọ̀púpọ̀; wọ́n yọ́ kúrò wọ́n sì padà sí ìlú wọn.