Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Medo-Persian Kingdom: Divided into many provinces
Àwọn ẹsẹ nípa Divided into many provinces
Èyí ni ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìgbà Ahaswerusi, tí ó jẹ ọba lórí ẹ̀tàdínláàdóje (127) ìletò bẹ̀rẹ̀ láti India títí ó fi dé Etiopia.
Ó dára lójú Dariusi láti yan ọgọ́fà àwọn baálẹ̀ sórí ìjọba,