Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Medo-Persian Kingdom: Were exceeding rich

2 ẹsẹ · 34 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Were exceeding rich

  1. Ó ṣe àfihàn púpọ̀ ọrọ̀ ìjọba rẹ̀ àti dídán àti ògo ọláńlá rẹ̀ fún ọgọ́sàn-án ọjọ́ gbáko.

  2. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí ó sùn nínú erùpẹ̀ ilẹ̀ ni yóò jí: àwọn mìíràn sí ìyè àìnípẹ̀kun, àwọn tókù sí ìtìjú àti sí ẹ̀gàn àìnípẹ̀kun.