Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Medo-Persian Kingdom: Darius Hystaspes
Àwọn ẹsẹ nípa Darius Hystaspes
Nígbà náà ni ọba Dariusi pàṣẹ, wọ́n sì wá inú ilé ìfí nǹkan pamọ́ sí ní ilé ìṣúra ní Babeli.
Dariusi ará Media sì gba ìjọba nígbà tí ó di ọmọ ọdún méjìlélọ́gọ́ta.