Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Aaron: Descendants of

19 ẹsẹ · 27 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Descendants of

  1. Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbìnrin Amminadabu tí í ṣe arábìnrin Nahiṣoni, ó sì bí Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.

  2. Eleasari ọmọ Aaroni fẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin Putieli ní ìyàwó, ó sì bí Finehasi fún un. Ìwọ̀nyí ni olórí àwọn Lefi ni ìdílé ìdílé.

  3. Àwọn ọmọ Amramu: Aaroni, Mose àti Miriamu. Àwọn ọmọkùnrin Aaroni: Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.

  4. Eleasari jẹ́ baba Finehasi, Finehasi baba Abiṣua

  5. Abiṣua baba Bukki, Bukki baba Ussi,

  6. Ussi baba Serahiah, Serahiah baba Meraioti,

  7. Meraioti baba Amariah, Amariah baba Ahitubu

  8. Ahitubu baba Sadoku, Sadoku baba Ahimasi,

  9. Ahimasi baba Asariah, Asariah baba Johanani,

  10. Johanani baba Asariah. (Òhun ni ó sìn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà nínú ilé Olúwa tí Solomoni kọ́ sí Jerusalẹmu).

  11. Asariah baba Amariah Amariah baba Ahitubu

  12. Ahitubu baba Sadoku. Sadoku baba Ṣallumu,

  13. Ṣallumu baba Hilkiah, Hilkiah baba Asariah,

  14. Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki.

  15. A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari.

  16. Wọ̀nyí ni àwọn ìránṣẹ́ Aaroni: Eleasari ọmọ rẹ̀, Finehasi ọmọ rẹ̀, Abiṣua ọmọ rẹ̀,

  17. Bukki ọmọ rẹ̀, Ussi ọmọ rẹ̀, Serahiah ọmọ rẹ̀,

  18. Meraioti ọmọ rẹ̀, Amariah ọmọ rẹ̀, Ahitubu ọmọ rẹ̀,

  19. Sadoku ọmọ rẹ̀ àti Ahimasi ọmọ rẹ̀.