Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Holy Spirit: Spirit of judgment

2 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Spirit of judgment

  1. Olúwa yóò wẹ ẹ̀gbin àwọn obìnrin Sioni kúrò yóò sì fọ gbogbo àbàwọ́n ẹ̀jẹ̀ kúrò ní Jerusalẹmu pẹ̀lú ẹ̀mí ìdájọ́ àti ẹ̀mí iná.

  2. Òun yóò sì jẹ́ ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo fún ẹni tí ó jókòó ní ìtẹ́ ìdájọ́ àti orísun agbára fún àwọn ẹni tí ó ń dá ogun padà ní ẹnu ibodè.