Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Holy Spirit: Spirit of wisdom

2 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Spirit of wisdom

  1. Ẹ̀mí Olúwa yóò sì bà lé e, ẹ̀mí ọgbọ́n àti ti òye, ẹ̀mí ìmọ̀ràn àti ti agbára, ẹ̀mí ìmọ̀ àti ti ìbẹ̀rù Olúwa.

  2. Mo sì ń béèrè nígbà gbogbo pé kí Ọlọ́run Jesu Kristi Olúwa wa, Baba ògo, lè fún yín ni Ẹ̀mí nípa ti ọgbọ́n àti ti ìfihàn kí ẹ̀yin kí ó tún lè mọ̀ ọ́n sí i.