Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Holy Spirit: Spirit of the Lord God

1 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Spirit of the Lord God

  1. Ẹ̀mí Olúwa Olódùmarè wà lára mi nítorí Olúwa ti fi àmì òróró yàn mí láti wàásù ìyìnrere fún àwọn tálákà. Ó ti rán mi láti ṣe àwòtán oníròbìnújẹ́ láti kéde ìdásílẹ̀ fún àwọn ìgbèkùn àti ìtúsílẹ̀ kúrò nínú òkùnkùn fún àwọn ẹlẹ́wọ̀n,