Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Holy Spirit: Spirit of revelation
Àwọn ẹsẹ nípa Spirit of revelation
Mo sì ń béèrè nígbà gbogbo pé kí Ọlọ́run Jesu Kristi Olúwa wa, Baba ògo, lè fún yín ni Ẹ̀mí nípa ti ọgbọ́n àti ti ìfihàn kí ẹ̀yin kí ó tún lè mọ̀ ọ́n sí i.