Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Root of David
Àwọn ẹsẹ nípa Root of David
“Èmi, Jesu, ni ó rán angẹli mi láti jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí fún yin ní tí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti irú-ọmọ Dafidi, àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tí ń tàn.”