Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Prophet

2 ẹsẹ · 117 abala

Wá "Titles and Names of Christ"

Àwọn ẹsẹ nípa Prophet

  1. Ó sì bi wọ́n pé, “Kín ni?” Wọ́n sì wí fún un pé, “Ní ti Jesu ti Nasareti, ẹni tí ó jẹ́ wòlíì, tí ó pọ̀ ní ìṣe àti ní ọrọ̀ níwájú Ọlọ́run àti gbogbo ènìyàn,

  2. Nítorí náà, nígbà tí ọ̀pọ̀ nínú ìjọ ènìyàn gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, wọ́n wí pé, “Lóòótọ́ èyí ni wòlíì náà.”