Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: True God

1 ẹsẹ · 117 abala

Àwọn ẹsẹ nípa True God

  1. Àwa sì mọ̀ pé Ọmọ Ọlọ́run dé, ó sì tí fi òye fún wa, kí àwa lè mọ ẹni tí í ṣe òtítọ́, àwa sì ń bẹ nínú ẹni tí í ṣe òtítọ́, àní, nínú Ọmọ rẹ̀, Jesu Kristi. Èyí ni Ọlọ́run òtítọ́, àti ìyè àìnípẹ̀kun.