Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Captain of salvation
Àwọn ẹsẹ nípa Captain of salvation
Nítorí pé ó yẹ fún Ọlọ́run, nítorí nípasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo ṣẹ̀ wà, láti mú àwọn ọmọ púpọ̀ wá sínú ògo, láti ṣe balógun ìgbàlà wọn ni àṣepé nípa ìjìyà.