Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Lion of the tribe of Judah
Àwọn ẹsẹ nípa Lion of the tribe of Judah
Ọ̀kan nínú àwọn àgbà náà sì wí fún mi pé, “Má ṣe sọkún: kíyèsi i, kìnnìún ẹ̀yà Juda, Gbòǹgbò Dafidi, tí borí láti ṣí ìwé náà, àti láti tú èdìdì rẹ̀ méjèèje.”