Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Root of Jesse
Àwọn ẹsẹ nípa Root of Jesse
Ní ọjọ́ náà, gbòǹgbò Jese yóò dúró gẹ́gẹ́ bí àsíá fún gbogbo ènìyàn, àwọn orílẹ̀-èdè yóò pagbo yí i ká, ibùdó ìsinmi rẹ̀ yóò jẹ́ èyí tí ó lógo.