Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Christ: Mighty One of Jacob
Àwọn ẹsẹ nípa Mighty One of Jacob
Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè a ó sì fun ọ́ ni ọmú àwọn ọba. Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé, Èmi Olúwa, èmi ni Olùgbàlà rẹ, Olùdáǹdè rẹ, Alágbára ti Jakọbu.