Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sidonians: Zidon

2 ẹsẹ · 30 abala

Wá "The Sidonians"

Àwọn ẹsẹ nípa Zidon

  1. Olúwa sì fi wọ́n lé Israẹli lọ́wọ́. Wọ́n ṣẹ́gun wọn, wọ́n sì lépa wọn ní gbogbo ọ̀nà títí dé Sidoni ńlá, sí Misrefoti-Maimu, àti sí àfonífojì Mispa ní ìlà-oòrùn, títí tí kò fi ku ẹnìkankan sílẹ̀.

  2. Ó sì lọ sí Abdoni, Rehobu, Hammoni àti Kana títí dé Sidoni ńlá.