Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sidonians: Territory of, to be given to Nebuchadnezzar, king of Babylon

2 ẹsẹ · 30 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Territory of, to be given to Nebuchadnezzar, king of Babylon

  1. Kí o rán ọ̀rọ̀ sí ọba ti Edomu, Moabu, Ammoni, Tire àti Sidoni láti ọwọ́ àwọn ikọ̀ tí ó wá sí Jerusalẹmu sọ́dọ̀ Sedekiah ọba Juda.

  2. Nísinsin yìí, Èmi yóò fa gbogbo orílẹ̀-èdè rẹ fún Nebukadnessari ọba Babeli ìránṣẹ́ mi; Èmi yóò sì mú àwọn ẹranko búburú wọ̀n-ọn-nì jẹ́ tirẹ̀.