Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Separation between the outer or Gentile court and that of the Jews alluded to

2 ẹsẹ · 49 abala

Wá "The Second Temple"

Àwọn ẹsẹ nípa Separation between the outer or Gentile court and that of the Jews alluded to

  1. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí nínú Kristi Jesu ẹ̀yin tí ó ti jìnà réré nígbà àtijọ́ rí ni a mú súnmọ́ tòsí, nípa ẹ̀jẹ̀ Kristi.

  2. Nítorí òun ni àlàáfíà wa, ẹni tí o ti ṣe méjèèjì ni ọ̀kan, tí ó sì ti wó ògiri ìkélé ti ìkórìíra èyí tí ń bẹ láàrín yín.