Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Solomon's porch connected with
Àwọn ẹsẹ nípa Solomon's porch connected with
Jesu sì ń rìn ní tẹmpili, ní ìloro Solomoni.
Bí arọ ti a mú láradá sì ti di Peteru àti Johanu mú, gbogbo ènìyàn jùmọ̀ súre tọ̀ wọ́n lọ ni ìloro ti a ń pè ní ti Solomoni, pẹ̀lú ìyàlẹ́nu ńlá.