Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Joy of those who had not seen the first temple
Àwọn ẹsẹ nípa Joy of those who had not seen the first temple
Kò sí ẹni tí ó le mọ ìyàtọ̀ láàrín igbe ayọ̀ àti ẹkún, nítorí tí ariwo àwọn ènìyàn náà pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́. Wọ́n sì gbọ́ igbe náà ní ọ̀nà jíjìn réré.