Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Materials for building procured from Tyre and Sidon

1 ẹsẹ · 49 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Materials for building procured from Tyre and Sidon

  1. Nígbà náà ni wọ́n fún àwọn ọ̀mọ̀lé àti àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà ní owó, wọ́n sì tún fi oúnjẹ, ohun mímu àti òróró fún àwọn ará Sidoni àti Tire, kí wọ́n ba à le è kó igi kedari gba ti orí omi Òkun láti Lebanoni wá sí Joppa, gẹ́gẹ́ bí Kirusi ọba Persia ti pàṣẹ.