Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Beautiful gate of, mentioned
Àwọn ẹsẹ nípa Beautiful gate of, mentioned
Wọn sì gbé ọkùnrin kan ti ó yarọ láti inú ìyá rẹ̀ wá, tí wọ́n máa ń gbé kalẹ̀ lójoojúmọ́ ní ẹnu-ọ̀nà tẹmpili ti a ń pè ni Dáradára, láti máa ṣagbe lọ́wọ́ àwọn tí ń wọ inú tẹmpili lọ.