Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Second Temple: Prayed without, while the priest offered incense within
Àwọn ẹsẹ nípa Prayed without, while the priest offered incense within
Gbogbo ìjọ àwọn ènìyàn sì ń gbàdúrà lóde ní àkókò sísun tùràrí.
pé, “Àwọn ọkùnrin méjì gòkè lọ sí tẹmpili láti gbàdúrà, ọ̀kan jẹ́ Farisi, èkejì sì jẹ́ agbowó òde.