Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sea: Measures the waters of

1 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Measures the waters of

  1. Ta ni ó tiwọn omi nínú kòtò ọwọ́ rẹ̀, tàbí pẹ̀lú ìbú ọwọ́ rẹ̀ tí ó wọn àwọn ọ̀run? Ta ni ó ti kó erùpẹ̀ ilẹ̀ ayé jọ nínú apẹ̀rẹ̀, tàbí kí ó wọn àwọn òkè ńlá lórí ìwọ̀n àti òkè kéékèèké nínú òsùwọ̀n?