Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sea: (Covered with waters,) of the diffusion of spiritual knowledge over The earth in the latter days

2 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Covered with waters,) of the diffusion of spiritual knowledge over The earth in the latter days

  1. Wọn kò ní ṣe ni léṣe tàbí pa ni run ní gbogbo òkè mímọ́ mi, nítorí gbogbo ayé yóò kún fún ìmọ̀ Olúwa gẹ́gẹ́ bí omi ti bo Òkun.

  2. Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo Olúwa, bí omi ti bo Òkun.