Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: The efficacy of faith

2 ẹsẹ · 46 abala

Wá "The Resurrection of Christ"

Àwọn ẹsẹ nípa The efficacy of faith

  1. Bí Kristi kò bá sì jíǹde, ǹjẹ́ asán ni ìwàásù wà, asán sì ni ìgbàgbọ́ yín pẹ̀lú.

  2. bí a kò bá sì jí Kristi dìde, asán ní ìgbàgbọ́ yín; ẹ̀yin wà nínú ẹ̀ṣẹ̀ yín síbẹ̀.