Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: Mary Magdalene

2 ẹsẹ · 46 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Mary Magdalene

  1. Nígbà tí Jesu jíǹde ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ní ọjọ́ kìn-ín-ní ọ̀sẹ̀, ó kọ́ fi ara hàn fun Maria Magdalene, ni ara ẹni tí ó ti lé ẹ̀mí Èṣù méje jáde.

  2. Maria Magdalene wá, ó sì sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, “Òun ti rí Olúwa!” Àti pé, ó sì ti fi nǹkan wọ̀nyí fún òun.